16.01President Bola Ahmed Tinubu
Renewed Hope: àwọn àtúnṣe owó-orí tí Lagos Chamber ti kí káàbọ̀ nítorí pé wọ́n ń kojú owó-orí àsanléraléra (multiple taxation), àti Electricity Act 2023 (Òfin Iná Mànàmáná) tí ó jẹ́ kí Èkó lè ṣàkóso ọjà iná mànàmáná tirẹ̀.




